Hymn 39
Eniti enyin fe lairi.
Meter: S.M & Refrain
Scripture: 1 Peter 1:8
1
fEyin te fe Oluwa,
E fi ayo yin han,
E jumo ko orin didun,
E jumo ko orin didun
K’e si y’ite na ka,
K’e si y’ite na ka
CHORUS
FfA nyan lo si Sion’
Sion’ to l’ewa jule
A nyan goke lo si Sion’,
Ilu Olorun t’o l’ewa
2
fJe k’awon ni ma korin
Ti ko m’Olorun wa,
Sugbon awon omo Oba,
Sugbon awon omo Oba,
Y’o royin ayo won,
Y’o royin ayo won.
3
Oke Sion’l’o nmu
Egberun adun wa
Ki a to de gbangba orun
Ki a to de gbangb’orun
Pelu ‘ta wura re,
Pelu ‘ta wura re.
4
mfNje ka ma korin lo,
CrK’omije gbogbo gbe
FA nyan n’ile Immanuel’
A nyan n’ile Immanuel’,
FfS’aye didan loke,
S’aye didan loke