Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 394

Kiyesii, emi mbo kankan; ere mi si mbe Pelu mi.

Meter: 10.7.10.7. & Ref.

Scripture: Ifi. 22:12.

1

crGba Jesu de lati fere fun wa,

Yala osan tab’ale,

Y’o ha ba wa, ka ma foto sona,

K’atupa wa si ma jo?

CHORUS

mfA ha le wipe, a se tan, ara,

Fun ’le wa didan l’oke?

Wi, y’O ha ba ’WO at’emi nsona?

Nsona, nsona n’gb’Oluwa o de?

2

mpNje bo ba je oro kutukutu,

T’O ba pe wa ni kokan,

’Gbat’ a ba da Talenti wa pada,

Y'O ha wi fun Q, “o seun?”

3

diA ha soto s’eyi t’O fi fun wa?

Gbogbo ipa wa la nsa?

Ti ko ba si ’dalebi l’okan wa

f’Simi ologo lao ni

4

mf’Bukun l’awon ti Krist’ ri to nsona,

Won o pin nin’ogo Re;

Bi l’aro tabi oganjo oru

Y’O ha ba wa be nsona?