Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 396

Pelu ipinnu okan, e fi ara mo Oluwa

Meter: 7.5.7 .6. & Ref

Scripture: Ife A. 11:23.

1

mfDuro pelu okan kan,

Se ’fe Olorun;

Yin awon olotito

Awon egbe Daniel.

CHORUS

crSe gegebi Daniel;

Ma wo enikan;

Ni ero rere l’okan

Si je ki aye mo

2

mpOpo akin lo nsegbe

Won ko to duro;

crBi won wo egbe Daniel

Won ba ja f’Olorun.

3

mfOpolopo omiran

Ti nhale kiri

Ni iba subu lule

B’egbe Daniel ko won.

4

fGb’opagun ’hinrere ga,

E ma segun nso;

Pe ogun esu nija;

Ho ye f egbe Daniel.