Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 397

E wo iru ife ti Baba fife wa

Meter: 7.6.7.6.8.8.8.7 & Ref

Scripture: Jn. 3:1.

1

fItan iyanu t’ife!

SO fun mi l’ekun si,

Itan iyanu t'ife

E gbe orin n aga!

Awon Angeli nroyin Re,

Awon Oluso si gbagbo;

Elese, iwo ki yo gbo

Itan iyanu t’ife

CHORUS

ffIyan! Iyanu! Iyanu!

Itan Iyanu t’ife

2

Itan iyanu t’ife

B’iwo tile sako;

Itan iyanu t’ife,

Sibe o npe loni;

crLat’ori oke Kalfari,

Lati orisun didun ni,

Lati isedale aye,

Itan iyanu t’ife.

3

fItan iyanu t’ife,

Jesu ni isimi;

Itan iyanu t’ife,

Fun awon oloto

To sun ni ile nla orun

Pel’awon to saju wa lo;

Won nko orin ayo orun

Itan iyanu t’ife.