Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 408

Jesu si wifun u pe, Riran; igbagbo re gba o la

Meter: 10.11.10.8.D.

Scripture: Lk. 18:42

1

crAfoju agbe na, wa leba ona

Titi Jesu fi wa, to wa s’ona na;

fInure si dun s’agbara Olorun,

'Gba Jesu gb’ona na koja.

crEbi on ese njoba laye mi,

Ki Jesu ko to gba ona mi koja;

mfNisisiyi ayo at’alafia de,

’Gba Jesu gb’ona mi koja.

2

mfGbolohun kan lat’enu Oluwa

Lo l’agbe na loju, gba Jesu nkoja;

Igbagbo agbe na nin’oro na

Fi imole kun okan re.

3

fMo gbo iro didun ti angeli,

’Gba Jesu nkoja to ngb’ona mi koja;

Bi won ti nfayo korin ’rapada

’Gba Jesu ngb’ona mi koja.

4

mfElese wa sodo Olugbala,

Ka we o nu kuro ninu ese re;

Jeki ’mole Oluwa wonu re,

Gba Jesu gb’ona yen koja.