Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 409

Awa o tun nkan yi gbo li enu re.

Meter: 11.11.11.11.10.9.11.11.&Ref.

Scripture: lse. A. 17:32

1

mpSo fun wa b’o ti se gba idariji?

Awa tun nfe gbo itan na lekan si:

Bo se wa sib’agbelebu fun ’gbala,

Awa tun nfe gbo itan na lekan si:

O ha nrin n’nu’mole ibukun Re?

O ha bo ninu ebi gbogbo?

mfKrist’ ha je ayo, orin re n’gbagbogbo?

Awa tun nfe gbo itan na lekan si.

CHORUS

mfJo, tun itan na so fun wa,

(Jo tun itan na so fun wa lekan si)

Tun itan na so fun wa,

(Jo, tun itan na so fun wa lekan si)

fItan didun ti ibukun,

Yio ran o lowo de ogo;

Awa tun nfe gbo itan na lekan si.

2

mfSo fun wa: Jesu ha mba o sise bi?

Awa tun nfe gbo itan na lekan si;

Sp fun wa: O ha ngbe o li apa Re?

Awa tun nfe gbo itan na lekan si;

Ko tun si ore, ti o dabi Re

To le mu o la isoro ja;

fJek’ araye gbo ohun t’O se fun o

Awa tun nfe gbo itan na lekan si.

3

mfO ha ti korin ’bukun bi eyi ri?

Awa tun nfe gbo itan na lekan si:

fOrin ti o dun ju ala didun lo,

Awa tun nfe gbo itan na lekan si;

Opo lo ti nwa isimi kiri,

T’ibanuje gori okan won,

fKede Jesu fun won l’oro tab’orin;

Awa tun nfe gbo itan na lekan si.

4

mpSo t’ijakadi re at’isegun re,

Awa tun nfe gbo itan na lekan si;

Yo ran awon to sese gbagbp LOWO,

Awa tun nfe gbo itan na lekan si;

crOgun orun apadi la mba ja,

Laipe a o ba Jesu joba,

Eyin ta ra pada, e mu eso wa

Awa tun nfe gbo itan na lekan si.