Hymn 41
E ma ba ara nyin soro ninu psalmu, ati orin iyin ati orin Emi.
Meter: 13.9.13.9 & Ref.
Scripture: Efe. 5:9
1
mfKo su wa lati ma ko orin igbani
FOgo f’Olorun aleluya!
A le fi igbagbo korin na s’oke kikan.
fOgo f’Olorun aleluya!
A le fi igbagbo korin na s’oke kikan.
CHORUS
FfOgo f’Olorun, Aleluya
MfOmo Olorun ni eto lati bu s’ayo
Pe ona yi nye wa si,
Okan wa ns’aferi Re;
Nigb’o se a o de afin Oba wa Ologo
FOgo f’Olorun, Aleluya!
2
mfAwa mbe n’nu ibu ife t’o ra wa pada,
FOgo f’Olorun Aleluya!
MfAwa y’o fi iye goke lo s’oke orun;
FOgo f’Olorun, Aleluya!
3
mfAwa nlo si afin kan ti a fi wura ko,
FOgo f’Olorun Aleluya!
Nibiti ao ri Oba Ogo n’nu ewa Re,
FfOgo f’Olorun, Aleluya!
4
mfNibe ao korin titun t’anu t’O Da wa n de,
FOgo f’Olorun Aleluya!
Nibe awon ayanfe yo korin ‘yin ti Krist;
FfOgo f’Olorun, Aleluya!