Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 412

Yara lati ran mi lowo Oluwa igbala mi:

Meter: C.M.

Scripture: OD. .18:22

1

mpWa, Oluwa l’anu tun wa,

Pelu ’pa 'p’okan da;

Ongbe ojo np’oko Sion,

Masai ro s’ori re.

2

pOkan wa kun fare kikan,

Lati ri b’elese,

Ti nte si iku ailopin,

Li airi iranwo.

3

p“Jesu, wa pelu’pa’soji,”

L’awon eeyan Re nke

Mu ’gbala wa ni sa anu,

Majek’ elese ku.

4

mfJek’ elese ro s’ile Re,

Ki won ho isegun.

crGbana l’edun wa y’o d’ayo.

Ekun, d’orin iyin.