Hymn 413
On o si fun nyin ni olutunu miran.
Meter: L.M.
Scripture: Jn. 14:16
1
mpGbo l’or’ ite Re. Alade,
F’oniruru ’bukun ranse,
B’awon omo Re ti nwa O,
Gb’adura t’oro Re ko ni.
2
mpWa, Emi Mimo lat’oke,
F’ife kun okan t’o tutu;
A! s’okan okuta d’eran,
K’O jek’ ipa Re di mimo.
3
pSoro, oju t’o da yio sun
Ekun ’robinuje jade;
Won yo si figbona okan
Wa ore ti won ko nani.
4
mfA! jek’opo awon mimo
Duro n’ilekun ile Re;
diK’olukuluku se ’tara
Lati f’ara rubo fun O.