Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 417

Biko sepe a tun eniyan bi, on ko le ri ijoba Olorun.

Meter: 11.11.11.6. & Ref

Scripture: Jn. 3:3

1

mfIjoye kan to Jesu wa li ale,

Lati bere ona ’gbala on ’mole;

Olukoni dahun l’oro oto pe,

mp“Ao le sai tun yin bi”

CHORUS

crAo le sai tun yin bi” (2)

Otito li oro na ti mo so pe:

cr“A o le sai tun yin bi”

2

mpEyin omo eniyan, e gbo oro

Ti Jesu Oluwa so pelu edun

Mase je k’oro na bo s’asan fun yin

Ao le sai tun yin bi.

3

mfEyin te nfe de ’bi simi ogo yi

Lati ba awon mimo korin 'bukun:

Bi e ba fe gba lye ainipekun

Ao le sai tun yin bi

4

mpOlufe t'okan re nsaferi jojo

Le ma w’ona re ni ibode orun;

Nje fetisi ohun orin jeje yi:

pAo le sai tun yin bi