Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 418

Emi o si bere lowo Baba, On O si fun yin li Olutunu miran

Meter: 12.12.12.6.D.

Scripture: Jn. 14:16

1

fTan ihin na kale, jakejado aye,

K’awon ti eru npa, mo pe igbala de:

mfK’awon ti se ti Krist’, so ihin ayo na,

Olutunu ti de.

CHORUS

mfOlutunu ti de, Olutunu ti de,

Emi lat-oke wa, ileri Baba wa;

ffan ihin na kale, jakejado aye,

Olutunu ti de.

2

mfOba awon oba, wa fiwosan fun wa,

O wa ja ide wa, O mu igbala wa,

K’olukuluku wa, korin isegun pe: Olutunu ti de.

3

ffIfe iyanu nla, a! mba le royin na,

Fun gbogbo eniyan, ebun or’-ofe Re;

mfEmi omo egbe, di omo igbala,

Olutunu ti de

4

fGbe orin ’yin soke, s’Olurapada wa,

K’awon mimo loke, jumo ba wa gberin

ffYin ife Re titi, ife ti ko le ku,

Olutunu ti de.