Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 419

Nwon o ma Soro ogo ijoba Re, n won o si ma soro agbara Re.

Meter: L.M.

Scripture: OD. 145:11

1

mfEmi anu oto, ife,

Ran agbara Re toke wa;

crMu lyanu ojo oni

De opin akoko gbogbo.

2

fKi gbogbo orile ede

Ko orin ogo Olorun;

Ki a si ko gbogbo aye

N'ise Olurapada wa.

3

mpOlutunu at’Amona,

crJoba Ijo Eniyan Re;

mfK'araye mo ibukun Re,

Emi anu, oto ife.