Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 420

Oluwa, Olorun Olodumare njoba.

Meter: 7.7.7.7.D.

Scripture: Ifi. 19:6

1

fGbo! orin ti Jubeli,

O dabi sisan ara;

Tabi bi kikun okun,

’Gbat’ igbi re ba nlu ’le;

ffAleluya! Olorun

Olodumare joba;

ffAleluya! k’oro na

Dun yi gbogbo aye ka.

2

fAleluya! gbo iro

Lati aye de orun,

Nji orin gbogbo eda,

L’oke, n’isale, yika,

Wo Jehofa ti sete,

pIda w’ako; O pase,

Awon ijoba aye

Di ijoba Omo Re.

3

Yo joba yi aye ka,

Pelu agbara nlanla;

Yo joba’gbati orun

At’aye ba koja lo:

pOpin de: lab’opa Re

ppL’ota eniyan subu:

ffAleluya! Olorun

Ni gbogbo l’ohun gbogbo.