Hymn 421
Lojojumo li a o si ma yin I.
Meter: 7.6.7.6.D
Scripture: OD. 72:15
fAlafia fun Jesu
Omo nla Dafidi.
Ni akoko ti a yan,
N'igba Re bere;
mfO de lati tan iya,
Lati tu igbekun,
Lati mu ese kuro.
Yo joba l’aisegbe
mfO mbo wa pelu’ranwo,
Fun awon ti njiya,
Yo ran alaini lowo,
Yo gb’alailera ro;
crYo f’orin dipo ose,
Okun yo di ’mole
F’okan ebi ti nku lo.
To s’owon loju Re.
mpYo s’okale bi ojo
Sori ile aye:
Ife, ayo, ireti,
So jade l’ona Re;
mfAlafia yo kede Re
Lori awon oke,
Ododo b’isun omi
Yo toke san sile.
diAraba, alarinkiri,
Yio wole fun U;
Alejo Etiopea
Yio wa w’ogo Re:
mfOko okun o pade
Pelu ore isin:
Lati f’isura okun
Josin lab’ese Re
mpOba yio wole fun
T’awon ti turari
Gbogbo orile ede
Yo korin iyin Re
mfLojojumo l’adura
Yio ma goke lo;
Ijoba Re yo gb’ile
Ijoba ailopin.
fYo segun gbogbo ota
Yo joko n’ite Re;
Ogo Re yio ma ran,
Alabukun laelae
mfAyida aye ko le
Mu majemu Re ye,
Ife li oruko Re.
Ki o pada laelae