Hymn 422
Ji, ji, gbe agbara WO, Iwo apa Olorun.
Meter: L.M.
Scripture: Isa. 51:9
1
fJi, apa Olorun, ko ji,
Gbe ’pa Re wo, mi orile
Ni sisin Re, je k’aye ri
Isegun ise anu Re.
2
ffT’ite Re wi fun keferi,
“Emi Jehofa Olorun”
Ohun Re yo d’ede won ru,
Yio wo pepe won lule.
3
mfKi ’gb’ojurere Sion’ de,
Ka m’eya Israel’ wa ’le;
N’iyanu ka foju wa ri
Keferi, Ju, l’agbo Jesu.
4
fOlugbala kede’fe Re
L’orile at’ede gbogbo;
Ki gbogb’ ota wole fun O
Ki won gba Jesu l’Oluwa.