Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 423

Wa, ki o si ran wa lowo

Meter: 7.6.7.6.D.

Scripture: lse. A. 16:9

1

mfLat’oke tutu Grinland,

Lati okun India;

Ni b'odo orun Afrik’

Nsan 'yanrin wura won;

Lat’ opo odo ’gbani;

Lati igbe ope,

Wpn npe wa k'agba le won,

L’ewon sina won.

2

Afefe orun didun,

Nfe je ni Srilanka;

Bi ohun ta nri dara.

diEniyan lo buru;

mpLasan, lasan l'Olorun

Nt’ebun Re gbogbo Ka!

Keferi, ni ’foju won

Nwole bo okuta.

3

mpNje awa ti a moye

Nipa ogbon orun,

O to ka f’imole du

Awon to wa l’okun

ffIgbala A! Igbala!

Fon rere ayo na

Titi gbogbo orile

Yoo mo Messiah.

4

fEfufu, mu ’hin re lo,

Ati eyin odo,

Titi bi okun ogo

Yo tan yi aye ka;

Tit’Odagutan ta pa

Fun irapada wa

ffYio pada wa joba,

Lalafia laelae.