Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 424

Wasu oro na.

Meter: L.M.

Scripture: II Tim. 4:2

1

mfKeferi nsegbe l’ojojo,

Egbegberun lo nkoja lo;

fMura Kristian s’ igbala won.

Wasu fun won, ki won to ku.

2

fE yonda owo, at’ebun

At’emi yin, ki won le ye;

Jesu se ohun nla fun yin,

Kil’ohun te ki o se fun.

3

Emi Oluwa, fo kiri,

Jake-jado ile aye;

Ko awon om’Olorun jo

Lati gbogbo oril’-ede.