Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 428

Ki ijoba Re de.

Meter: 6.6.6.6.

Scripture: Mat. 6:11

1

mfKrist’ ki ‘joba Re de,

Ki ase Re bere;

F’opa irin Re fo

Gbogbo ipa ese

2

pIjoba ife da?

Ati t’alafia;

’Gba wo ni irira

Yio tan bi t’orun?

3

Akoko na ha da

T’ote yio pari;

Ika ati ’reje,

Pelu ifekufe?

4

mpOluwa, jo dide

Wan’nu agbara Re;

Fi ayo fun awa

Ti o ns’aferi Re.

5

pEda ngan oko Re,

Koko nje agbo Re,

Iwa ’tiju pupo

Nfihan pe ’fe tutu.

6

Okun bole sibe,

Ni ile keferi,

crDide’Rawo oro,

ffDide mase wo mo