Hymn 429
E wi larin awon keferi pe Oluwa joba
Meter: 13.6.13.6.13.13.13.15.13.6.13.6.
Scripture: OD. 96:10
Wi jade larin keferi p'Oluwa l’Oba,
Wi jade! Wi jade!
Wi jade forile-ede mu ki won korin,
Wi jade! Wi jade!
crWi jade tiyin tiyin pe, On o ma po si,
Pe, Oba nla Ologo l’Oba alafia,
ffWi jade tayotayo bi iji tile nja
Pe O joko lor’isan omi, Oba wa titi lae.
Wi jade larin keferi pe, Jesu njoba,
Wijade! Wijade!
crWi jade f’orile-ede mu k’ide won ja,
Wijade! Wijade!
pWi jade fun awon ti nsokun pe, Jesu ye,
Wi jade f’alare pe, O nfun ni n’isimi,
Wi jade f’elese pe O wa lati gbala;
Wi jade fun awon ti nku pe, O ti segun iku.
fWi jade larin keferi Krist’ njoba loke,
Wijade! Wijade!
Wi jade fun keferi ife n’ijoba Re,
Wijade! Wijade!
crWi jade l’ona opopo l’abuja ona
Je ko dun jakejado ni gbogbo agbaye,
ffB’iro omi pupo ni k’iho ayo wa je,
Titi gbohun-gbohun yo fi gbe iro na de'kangun iye