Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 430

Nitori mi ati nitori ihinrere.

Meter: 8.7.8.7.D.

Scripture: Mk. 8:35

1

fTori Mi at’Ihinrere,

E lo so t’Irapada,

crAwon onse Re nke, “Amin”

fTire ni gbogbo ogo;

mfNwon nso t’ibi, t’iya, t’iku,

Ife etutu nla Re;

Nwon ka ohun aye s’ofo

fT’ajinde on'joba Re

2

fGbo, gbo, ipe ti Jubeli,

O ndun yi gbogb’aye ka,

crN’ile ati l’oju okun,

A ntan ihin igbala;

pBi ojo na ti n sun mole,

T’ogun si ngbona janjan,

fImole ila-orun na

Yo mo larin okunkun.

3

fSiwaju ati siwaju

Lao ma gbo, “Aleluya”

crIjo Ajagun yo ma yo

Pel’awon oku mimo,

A fo aso won n’nu eje,

Duru wura won si ndun,

ffAye at’orun d’ohun po,

Won nko orin isegun.

4

fO de Eni t’a nwona Re,

Eni ikehin na de.

Imanueli t’O d’ade,

Oluwa awon mimo,

crlye, Imole at’ife,

Metalokan titi lae;

ffTire ni ite Olorun

Ati t’odo Agutan.