Hymn 432
O ti ran mi lati kede idasile fun awon igbekun.
Meter: 6.6.6.6.8.8.
Scripture: Isa. 61:1
1
fE fun ’pe na kikan,
Ipe ihinrere;
K’o dun jake jado
L’eti gbogbo eda:
ffOdun idasile ti de
Pada elese, e pada.
2
Jesu Alufa wa
Ti s’etu lasepe:
Alare, e simi,
Asofo, tujuka.
3
mfFun’pe t’od’agutan
Tati pa setutu;
crJe ki agbaye mo
Agbara eje Re
4
Eyin eru ese;
E so ra yin d’omo;
Lowo Kristi Jesu,
E gb’ominira yin.
5
fGbo ’pe ihinrere,
Ihin ore-ofe;
Agba yin low’aye,
E wa ’waju Jesu.