Hymn 433
Emi yio tu ninu Emi mi sara eniyan gbogbo.
Meter: L.M.
Scripture: Ise A. 2:17
1
fEmi Olorun alaye,
N’nu ekun ore-ofe Re,
Nibit’ ese eeyan ti te,
Sokale s’ori iran wa.
2
mfF’ebun ahon, okan ife
Fun wa, lati Soro’fe Re;
K’ibukun at’agbara Re
Ba l’awQon to ngbo Oro na.
3
K’okun ka ’se ni bibo Re;
Ki ’daru dapo di tito;
F’ilera f’okan ailera,
Je ki anu bori ’binu.
4
mpEmi Olorun, jo pese
Gbogbo aye fun Oluwa,
crMi si won b’ afefe oro,
K’okan okuta le soji.
5
fBaptis’ gbogb’ orile-ede,
Royin ’segun Jesu yika;
Yin oruko Jesu l’ogo;
Tit’araye yo jewo Re.