Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 434

E ji iji ododo.

Meter: 8.8.8.6. & Ref.

Scripture: IKor.l5:34

1

fJi, so agbara Re d’otun

Gbe ’hamora ogun re WO;

A o segun gbogbo ota,

Kristi yo si joba.

CHORUS

ffKrist’ y’o joba

Krist’ y’o joba,

Ireti wa n’nu Re ko ye;

Krist’ y’o joba,

Krist’ y’o joba,

Krist’ y’o joba,

Ireti wan’nu Re ko ye

Krist’ y’o joba.

2

mpO ti pe t’awon Omo Re

Ti nse ’yapa lori eko;

Won gbagbe pe l’ori ’sokan

Ni On lo aye Re.

3

mfE papo li agbara Re,

Aye yin yo ,si je ere;

fLaipe e o ni isegun,

’Tori Krist’ y'o joba.

4

crO ye ka sise f’Oluwa,

Ise wa ko ni je asan;

mfA ko gbodo pada s'ehin,

’Tori Krist’ y’o joba.