Hymn 436
Ki ife ara Ki o wa titi.
Meter: D.C.M.
Scripture: Heb. 13:1
1
fIfe Olugbala a o f’ayo han,
Ki gbogb’ aye le ri,
Ayo 'simi, alafia
T'awon lo t'e O ni.
CHORUS
mfGbogbo aye, gbogbo aye,
Gbogbo, tile, t’okun (toke),
A fe gbogbo aye fun Krist’
K’orile d’ominira.
2
mfJe ki le soro ’hinrere
Titi gbogb’ okan wa
Pelu gbogb’ eni yi wa ka
Y’o fi gba O l’Oba.
3
fRan wa b’ina at’orun wa,
Ti mole re yo tan,
Tit’awon to wa n’n’okunkun
Yo ri imole na.
4
mfJe ki ’yanu or’ofe Re
Kun inu okan wa;
K’awa le fi itara lo
Lati se ’ranlowo.