Hymn 439
Ma ja ija rere ti igbagbo.
Meter: 7.7.11 .D. & Ref.
Scripture: 1 Tim. 6:12
1
fGbe asia na soke!
Si ma gbe lojojumo,
Titi gbogb’ agbara ibi yo wole!
fJeki o ma fe lele
Pelu ’hin Krist’ le gbala;
Gbe soke titi yo fi yi aye ka.
CHORUS
fGbe soke titi yo fi yi aye ka,
Titi agbara nla ibi yio fi wo;
Jeki o ma fe lele.
Pelu ’hin: Krist’ le gbala,
Gbe soke titi yo fi yi aye ka.
2
mfGbe asia, na soke,
Ni gbogb’ orile ede,
Ki a ma se ka asia na kuro;
fTiti aye yo korin
T’Imanueli, Oba won,
Gbe soke titi yo fi yi aye ka.
3
mfGbe asia na soke,
Ko ma dan ni gbogbo ’le
M’ojo na yara de t’yo ma fe lele:
crMu fo lat’okun d’okun,
Tit’ aye yo gba Kristi;
Gbe soke titi yo fi yi aye ka.