Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 444

imole lati mole si awon Keferi.

Meter: 8.7.8.7.8.7.

Scripture: Lk. 2:32

1

Wo! gbogbo ile okunkun,

Wo! okan mi, duro je:

Gbogbo ileri ni o nso

T’ojo ayo t’o logo;

Ojo ayo, ojo ayo,

K’owuro re yara de!

2

mfKi gbogbo ile agbaye

K’alaigbede gbogbo ri

Isegun nla t’o logo ni;

T’ori oke Kalfari;

K’ihinrere; k’ihinrere

Tan lat’ ilu de ilu.

3

Ijoba to wa l’okunkun,

Jesu, tan ’mole fun won

Lat’ ila-orun de ’WO re,

K’imole le okunlo;

K’irapada, k’irapada.

Ti a gba l’ofe b’ori.

4

Ma tan lo ‘WO ihinrere,

Ma segun lo, ma duro,

K’ijoba re ayeraye

Ma bi si, k’o si ma re;

Olugbala, Olugbala,

Wa joba gbogbo aye.