Hymn 448
Awon Oba Seba ati ti Seba yio mu ebun wa.
Meter: 6s. 4.
Scripture: OD. 72:10
1
Lati erekusu
De ikangun okun,
K’Oba juba Jesu.
Ki won mu ore wa
Ki Arab’ le
Orin orun;
K’ Afrika dapo
Gbe ’yin Rega.
2
Om’alade y’o sin
Won o mu ore wa
Lati yin agbara
Imanuel Oba ;
Ile jinjin
Yio josin
Aye y’o gba
Ase Re gbo