Hymn 451
Emi o si pelu enu re, Emi o si ko o li eyiti iwo o wi.
Meter: 6.6.6.6.D.
Scripture: Eks. 4:12
1
mfTan ’mole Re si wa
L’oni yi, Oluwa
Fi ara Re han wa
N’nu oro mimo Re:
Jo m’okan wa gbona,
Ka ma wo oju Re
K’awon ’mode le ko
Iyanu ore Re
2
mpMi si wa, Oluwa
Ina emi mimo;
crKa le fi okan kan
Gbe oruko Re ga;
JO fi eti igbo,
At’okan ironu,
Fun awon ti a nko
L’ohun nla t’O ti se.
3
mfBa ni so Oluwa,
Oro Re ti a nso;
Jeki eko wa je
Gegebi oro Re;
K’awon agutan Re
Le ma mo ohun Re;
Ibit’Onto won si
crKi won si le ma yo.
4
mfGbe ’nu wa Oluwa,
K’ife Re je tiwa;
Iwo nikan la o fi
Ipa wa gbogbo sin;
K’iwa wa je eko,
Fun awon omo Re,
diKo si ma kede Re
Ninu gbogbo okan.