Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 460

Oluwa ise Re ti PO to!

Meter: C.M.

Scripture: OD. 104:24

1

mfIwe kan wa ti kika re

Ko soro fun eeyan;

Ogbon ti awon to ka nfe

Ni Okan ti o mo.

2

mfIse gbogbo t’Olorun se

L’oke nile, n’nu wa;

A ko won sinu iwe na

Lati f’Olorun han.

3

Awosanma t’o ga julo,

Dabi ’fe Olorun

Labe eyi ti gbogb’eda

Mbe li alafia.

4

Okun, lati ayeraye,

Nfi egbarun ahon

Kede oko to ga julo

Pelu awon angeli.

5

mfIwo ti O jeki nle ri

Ohun to dara yi;

Fun mi l’okan lati wa O,

K’a ri O nibi gbogbo.