Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 461

Ilana re li o ti nse orin mi ni ile atipo mi.

Meter: CM

Scripture: OD. 119:54

1

fBaba orun nin’ oro Re

L’ogo ailopin ntan;

Titi lae la ma yin O

Fun Bibeli Mimo.

2

mpOpo ’tunu wa ninu re

Fun okan alare;

Gbogbo okan ti ongbe ngbe

Nri omi iye mu.

3

To wa s’orun ka le n’ipin

Nibi t’ayo gbe wa:

Mu wa de odo Olorun,

Ka simi n’nu Re lae.

4

mfIba le ma je ayo mi,

Lati ma ka titi;

crKi nma ri ogbon titun ko

N’nu re lojojumo.

5

mfOluwa Oluko orun,

Mase jina si mi:

Ko mi lati fe oro Re .

Ki nri Jesu nibe.