Hymn 463
Ma wi, Oluwa, nitori iranse Re ngbo,
Meter: 6.5.6.5.
Scripture: I Sam. 3:9
1
mpBami soro, Jesu,
Mo nduro de O;
KO mi ba ti nduro
Lati gbohun Re.
2
Ba mi so, Oluwa,
Ni wakati yi;
Jeki nri oju Re,
At’agbara Re.
3
Oro enu Jesu,
Oro iye ni;
Onje atorunwa,
Ma fi b’okan mi.
4
mfFi kun mi, Oluwa
Ekun Emi Re;
Bi iri lat’oke,
Jek’o ba le mi
5
mpMo f'ara mi fun O,
Ki nle je Tire;
Emi, okan, ara,
Fi mi se Tire.
6
crMa wi Oluwa, wi,
Iranse Re ngbo;
Emi nteti lele
Lati gbo 'ro Re
7
Fun mi ni imo si,
Ki nmo ife Re;
Ki gbogbo ife Re
Le se ninu mu.
8
Bi igi ti a gbin
Si eba odo;
Be ni ki aye mi
Ma mu eso wa.