Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 467

La mi li oju ki emi ki o le ma wo ohun iyanu wonni lati inu ofin re

Meter: C.M

Scripture: OD 119:18

1

mfBaba eda, n’nu Eni ti

A wa, a nrin, a nmi;

Ran ‘tansan orun sokale,

Wa mu wa laraya

2

p‘Gbat’ a nwa O n’nu oro Re,

Pelu iwariri

La wa l’oju, si je k’ a ri

Iyanu ofin Re

3

mpJeki Okunkun wa le ri

‘Mole ti ntan sansan;

Ran Emi ‘fihan sokale,

Fun wa l’eti ‘gboran

4

crMu ore Re ti a gbogbo

Koja niwaju wa;

Jek’ a r’oju Re n’nu Jesu,

K’a ko ohun aye.