Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 474

Mo ri Oro Re mo si je won.

Meter: C.M.

Scripture: Jer. 15:16

1

mfBibel’ iwe ayeraye!

Tani ler’idi re?

Tani le so idide re?

Tani le m’opin re?

2

fAsiri Olodumare;

Iko Oba orun;

ffIda t’o pa oro iku,

Aworan Olorun.

3

mfOkan ni O larin opo

Iwe aye ’gbani,

Iwo l’o s’ona igbala

Di mimo f’araye.

4

mfIsura ti Metalokan,

ffOba nla t ’ O gun wa;

Jo, tumo ara re fun mi,

Ki ’m’ye siyemeji.

5

Ki’m’ si O pelu adura,

Ki’m’ k’eko ninu re;

Iwo iwe ayeraye

F’ife Jesu han mi.