Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 480

Baptist won li oruko Baba ati ni ti Omo ati ni ti Emi mimo.

Meter: L.M.

Scripture: Mat. 28:19

1

mfWa Emi Mimo sokale

Oni baptisi okan wa;

M’edidi majemu Re wa,

K’O si se eri omi yi.

2

ffTu agbara nla Re jade,

K’O si won eje etutu;

Ki Baba, Omo at’Emi,

S’awon yi d’omo Olorun.