Hymn 482
Nitorina e LO, e ma ko orile-ede gbogbo, ki e si ma baptisi won ni oruko Baba, ati ni ti Omo ati ni ti Emi Mimo
Meter: 8.7.8.7.
Scripture: Mat. 28:19
1
mfE ni ’rele t’o nwa ’gbulu
Nip’eje Od’-agutan.
E gbo ohun isipaya,
Erin ’na ti Jesu rin.
2
mfGbo Olugbala t’O npe yin,
F’eti s’ohun Re orun,
diMa beru ibi t’o le de,
Nigbat’ eyan onu Re
3
mfJesu wipe, “Se ’tebomi
Fun awon t’o gba Mi gbo;’’
A te On papa bo ’mi ri,
Ninu odo Jordani.
4
mfEto ipase Re nihin,
To lehin laiduro pe;
E fi ayo gba ase Re,
Wo! Olori yin saju.