Hymn 485
Nje a si n baptismu sin wa PO pelu re sinu iku.
Meter: L.M.
Scripture: Rom. 6:4
1
mpAko ha gb’oro wuwo ni,
P’a sin wa pelu Oluwa?
P’a te wa ri sinu ’ku Re,
A si bo ara osi ‘le.
2
fOkan wa gba emi t’orun,
A gbe kuro ninu iku;
Beni Krist’ Jinde n’iboji,
O si mb'Oloorun gbe l’oke.
3
mpK’a ma jek'esu tun joba
Ninu ara iku wa mo,
Gbogbo ese ti a ti nda,
Ki yio j’oba l’ori wa mo.