Hymn 486
Enikeni ti o ba gbaagbo ki yio segbe, fugbon yio ni iye ti ko nipekun.
Meter: L.M.
Scripture: Jn. 3:16
1
mfOluwa orun at’aye!
Jesu, Omo ninu ara!
Emi Mimo fun ’toju wa!
Egbo, ki E si gb’eje wa.
2
mpA gba O, Jesu ti a pa,
A gba ’WO t’O r’oke orun;
Pelu Re a ti ku s’ese,
Okan wa si nfe ba O ji.
3
A gba ihinrere Re gbo,
A nlo, owo Re yio to wa;
L’odo Jordani a nw’ona
T’awon Tire gba d’odo Re
4
pNipa ’tebomi ami nla
Awa fi ara wa fun O
F’edidi te majemu na,
K’O gba wa la fun Tire.