Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 492

E ma se eyi ni iranti mi.

Meter: C.M.

Scripture: Lk. 22:19

1

mfGege bi oro ore Re,

Ninu irele nla;

Emi o se yi Oluwa,

pEmi o ranti Re.

2

mfAra Re ti a bu fun mi

Yio o je ounje mi;

Uno gba ago ibukun Re

pLati se ranti Re

3

mpMo le gbagbo Gethsemane,

Ti mo r’ijamu Re,

ppIya on ogun eje Re,

crKi nma si ranti Re.

4

Gba mo ba nwo agbelebu,

Ni oke Kalfari;

’WO Od’agutan Olorun

Dandan, un o ranti Re

5

mpUn o ranti gbogbo ’rora Re,

At’ ife Re si mi,

crBi o ku emi kan fun mi,

Emi o ranti Re.

6

ppGbati enu mi ba pamo,

Ti lye mi ba ra;

crTi o ba de n’ijoba Re,

Jesu jo ranti mi.