Hymn 496
Oluwa Odo tali awa o lo?
Meter: 7.7.7.7.D.
Scripture: Jn. 6:68
1
mfTal’ awa iba to lo
Biko s’ odo Re Jesu?
’Wo ti se imole wa,
At’iye ainipekun
mpEmi Re ti l’owo to
T’Emi Mimo nmi si wa?
Onje Re Atorunwa,
Li okan atunbi nfe.
2
mfIsraeli li atijo,
Won je manna, won si ku;
Awon t’o je l’ara Re
Won ki y’o kebi laelae
mpTal’ awa iba to lo
’Gbat’ ibi ba yi wa ka?
crBikos’ odo Re Jesu
’Wo tise iranwo wa.
3
mfTal’ o le we okan wa,
T’o si le gbo igbe wa?
Tani le kun okan wa
Olugbala, lehin Re,
fIyin at’ope fun O Titi,
’Wo Olorun mi;
Ninu Re le mi o ma wa,
Ma wa ninu mi titi.