Hymn 498
Ara mi tia fifun nyin ni eyi, E ma se eyi ni iranti mi.
Meter: 10.10.
Scripture: Lk. 22:19
1
mpSunmo ’hin, k’o gba Ara Oluwa,
K’o mu eje mimo t’a ta fun O
2
mpAra at’eje na l’o gba o la
crN’itura okan, f’ope f’Olorun.
3
fElebun igbala, Omo Baba,
Agbelebu Re fun wa n’isegun.
4
diA fi On rubo fun tagba tewe,
On tikare, l’ebo, On l’alufa.
5
mfOn l’Oludande, On ni Imole,
On nf’Emi ran awon tire lowo.
6
mpNje e fokan igbagbo sunmo, ’hin,
Ki e si gba eri igbala yi.
7
mfOn l’o nsakoso eeyan Re laye,
On l’o nf’ iye ainipekun fun wa.
8
fOn nfonje orun fawon t’ebi npa,
Omi iye fun okan ti n pongbe.
9
pOnidajo wa, Olugbala wa,
Pelu wa ni ase ife Re yi