Hymn 499
Enyin fi iku Oluwa han titi yio fide.
Meter: 7.7.7.D.
Scripture: I Kor. 11:26
1
crK’On t’o de, — je k’oro yi
Ma dun titi l’eti re;
Je ki sa a die t’o ku
Han gbangba daju fun O;
fRonu b’orun on ile
di‘Ti d’ehin gbat’O ba de.
2
pGbat’ awon ti a feran
BO si ’sinmi won loke,
T’o je pe aye wa pin,
Ti adun re si koro;
diE dakun, e ma b’ohun
crKiki k’On to de so ni.
3
mpIbanuje yi wa ka,
A ha fe k’o dinku bi?
Gbogbo eru iponju
Gbogbo ofo aye yi,
Iku, ofo on ’boji
pNso jeje pe, ’K’ On t’o de.
4
mfWo tabil’ ife t’a te,
Mu waini, si j’akara;
’Ranti didun, k’Oluwa
To pe wa s’onje orun,
pNi lat’aye ’mi l’orun,
crWo on pinya tit’ On fi de.