Hymn 500
Nwon si nrohin nkan ti o se li ona ati bi o ti di mimo fun won ni bibu akara
Meter: C.M.
Scripture: Lk. 24:25
1
mfF’arahan wa n’ibi onje,
Ma si se lo nihin;
Olugbala ba wa joko,
Ko si ba wa jeun.
2
fFi ife mimo ba wa jeun;
K’ara on eje Re,
Onje iye, waini t’orun
Ma bo wa titi lae.