Hymn 502
O fi eje Re we wa nu kuro ninu ese wa gbogbo.
Meter: 11.9.11.9. & Ref.
Scripture: Ifi. 1:5
1
mfO ti to Jesu lo fun ’wenumo bi?
A we O n’n’ eje Od’agutan?
Iwo ha gbekele ore-ofe Re?
A we O n’n’eje Od’agutan?
CHORUS
A we O n’nu eje
Ninu eje ti nwe okan mo?
Aso re ha funfun, o si mo laulau?
A we o n’n’eje Od’agutan?
2
mfO mba Olugbala rin l’ojojumo
A we'o n’n’eje Od’agutan?
O ha gbekele Eni t’a kan mo ’gi?
A we o n’n’eje Od’agutan?
3
mfAso re ha mo lati pade Jesu?
A fo mo n’n’ eje Od’agutan
Okan re ha mura fun ’le didan ni?
K’a we o n’n’eje Od’agutan?
4
mpBo ewu eri-ese si apakan,
K’a we o n’n’eje Od’agutan?
Isun kan san fun gbogbo okan aimo,
Jo lo we n’n’eje Od’agutan.