Hymn 505
Emi ki yio mu ninu eso ajara yi mo, titi yio fi di ojo na, nigbati emi o si ba nyin mu u ti titun ni ijoba Baba mi.
Meter: C.M.
Scripture: Mat. 26:29
1
mfOjo ko’ ase na leyi,
Mo f’ara mi fun yin
pE wo, mo feje mi fun yin,
Lati ra yin pada.
2
O di ’nu ’joba Baba mi,
Ki nto tun ba yin mu;
’Gbana ekun ko ni si mo,
A o ma yo titi.
3
mfTiti l’ao maje onje yi.
K’o to di igba na;
Ka gbogb’ aye l’opolopo
Y’o ma je, y’o ma mu'.
4
’Bukun atorunwa y’o ma
Wa lor’ awon t’o nje;
Uno gbe or’ite Baba mi
Ma pes’ aye fun won.
5
pSugbon nisisiyi, ago
crKikoro l’em’ o mu,
Emi o mu nitori yin,
ppAgo rora iku.
6
pE ko le mo banuje mi,
E ko ti r’ogo mi;
mfSugbon e ma s’eyi titi,
K’e ma fi ranti mi.