Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 506

Nitori eyi li eje mi ti majemu titun, ti a ta sile fun opo enia fun imukuro

Meter: S.M. & Ref.

Scripture: Mat. 26:28

1

mfIsin ’dapo mimo

Ore-ofe l’o je

K’a je akara, k’a mu wain’

N’iranti Re, Jesu.

CHORUS

Fun rant’ ebo mimo na,

Mimo na, mimo na,

L’awa pejo po fun l’oni

Lati f’lku Oluwa han

Titi Oun.....y'o fide;

Od’lnu Ijoba Baba mi

Ki nto tun ba yin mu;

N'iru 'dapo be ao ri idande gba

N'gba ba ro m’eje na,

Ogun esu le nde,

A o segun gbogbo won,

Nipa eje Jesu, Odagutan.

2

Eje ti nsan f’ese

L’a r’apere re yi;

Eri si ni li okan wa

Pe Iwo feran wa.

3

A! Eri die yi

Bi o ba dun bayi,

Y’o ti dun to loke orun

N’gba t’a ba r’oju Re.

4

Gbana ao mo daju

Pe aworan Re ni wa;

Gbogb’ona ore ’yanu Re

Nkede titi aye.