Hymn 507
Wo o, awa ti fi gbogbo re sile
Meter: 8.8.8.6. & Ref.
Scripture: Mat. 19:27
1
mpMo faye at’ife mi fun,
Od’agutan t’o ku fun mi;
Je ki nleje olotito
Jesu Olorun mi.
CHORUS
pUn o wa f’Eni t’O ku fun mi,
Aye mi yo si dun pupo,
Un o wa f’Eni t’O ku fun mi;
Jesu Olorun mi.
2
crMo gbagbo pe Iwo ngba ni,
’Tori ’Wo ku, k’emi le la;
Emi y’o si gbekele O,
Jesu Olorun mi.
3
mpIwo t’O ku ni Kalfari
Lati so mi d’ominira;
Mo yara mi s’oto fun O,
Jesu Olorun mi.