Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 508

Bikosepe enyin ba je ara Omo enia, ki enyin ki o si mu eje Re, enyin ko ni iye ninu nyin.

Meter: L.M.

Scripture: Jn. 6:53

1

mpJesu a teriba fun O

A mo p’O mu oro Re se

A gbo ohun Re a si si

Okan wa lati gba O si.

2

crWole wa, Alejo orun

Layo si ohun t’O fun wa

Ba wa je ninu ebun Re

So okan ’kanu d’ile Re.

3

Jo tewo gba adura wa

K’O si gba ebo iyin wa

F’omije wa s’iranti Re

Simi n’nu ’fe ’rapada Re.

4

mfK’ajoko labe iji Re

Pe wa l’ore at’ olufe

Je k’a je k’a si mu lofe

K’a ni ’telorun lodo Re.

5

mpJe k’a je ninu ore Re

K’a jeran Re k’a m’eje Re

Ohun mimu li eje Re

Onje orun li ara Re.

6

mfGbagbo nfonje orun bo wa

L’o nfi ore ofe to wa.

A nfi O s’onje lokan wa

A mo pe orun mbe n’nu Re.