Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 509

Sugbon ki olukuluku nyin ki o fe ran aya re be gege bi on tikara re.

Meter: 11.10.11.10.

Scripture: Efe. 5:33

1

mfIfe pipe, t’o tayo ero eda,

Niwaju Re l’a wole l’adura

Pe, ki ife ailopin le je t’awon

Ti IWO so d’okan titi aye.

2

mfIye pipe, ma je igbekele won

Fun ife on igbagbo ododo;

Fun ireti on emi ifarada,

Pelu ’fokantan lai beru iku.

3

crFun won l’ayo ti nbori ibanuje

Fun won l’alafia ti n m’aye dun,

Titi owuro ologo y’o fi mo;

Ojo ife on iye ailopin.