Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 510

Olorun si sure fun won.

Meter: 7.6.7.6.

Scripture: Gen. 1:28

1

mfIre t’a su ni Eden

N’igbeyawo ’kini;

Ibukun t’a bukun won

O wa sibe-sibe.

2

Sibe titi di oni

N’igbeyawo Kristiani;

Olorun wa l’arin wa,

Lati sure fun wa.

3

Ire ki won le ma bi

Ki won ko si ma re;

Ki won ni ’dapo mimo

T’enikan k’yo le tu.

4

pBa wa pe, Baba orun,

F’obirin yi f’oko;

Bi O ti fi Efa fun

Adam l’ojo ’kini.

5

pBa wa pe, Imanueli

crSi so owo won po;

B’eda meji ti papo

L’ara ijinle Re.

6

pBa wa pe, Emi mimo;

crF’ibukun Re fun won;

Si se won ni asepe

Gege b’O ti ma se.

7

mfFi won s’abe abo Re

K’ibi kan ma ba won;

’Gba won npara ile Re

Ma toju okan won.

8

Pelu won loj’aye won

At’oko at’aya;

Titi won o d’odo Re

N’ile ayo l’orun.