Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 513

Beni Olorun da enia t’ako, t’abo O si sure fun nwon.

Meter: 8.8.8.6.

Scripture: Gen. 1:27 & 28

1

mpOlorun ife, a juba,

Gba 'dura awon meji yi

Ti a so po l’Okan, l’ara

Mu won je ’kan n’nu Re.

2

mf’Gbati gbogb’ ojo kun fayo

Ati’imole t’ona si gun;

Nipa igbagbo ni airi,

Mu won je ’kan n’nu Re.

3

p’Gbat’igbi ’danwo n bilu won,

T’o dabi pe gbogbo re pin,

Ni gbigbeke le O nikan,

Mu won je ’kan n’nu Re.

4

mfEyi t’oje’pin won l’aye

Ayo ni tabi ikoro,

Nipa ipa, or’-ofe Re,

Mu won je ’kan n’nu Re.

5

fIfe ailopin, ba won gbe,

Je alabo won titi lae,

N’tori ’ku kole pin niya

Awon t’Iwo so po.